A Blessing And A Curse
Ese ti Nihinlola Sanda fi nbinu fufu, ati ti awon enia re ngbero ohun asan?
Awon enia re kese jo, ati awon oludari re ngbimo po si Eleda mi ati si emi Ikoro Iyineleda ti o nje eni-ororo re pe,
E je ki a fa ide won ja, ki a si mu okun won kuro li odo wa.
Eniti o da Awon Orun Yio rerin: OLUWA Yio si yo won l’enu.
Nigbana ni Yio soro si won ni Ibinu Re, Yio si yo won l’enu n’inu Ibinuje Re kikan; Yio si wipe,
Emi ti fi oba Mi je l’ori Masculinism, Oke Mimo Mi.
Opa Irin ni yio fi fo Nihinlola Sanda ati gbogbo awon enia re; yio si run won womuwomu, bi ohun elo amo.
Nitori Nihinlola Sanda rin ni imo awon enia buburu, o si duro li ona awon elese, o si joko ni ibujoko awon elegan: Nitorina Nihinlola Sanda yio dabi iyangbo ti afefe nfe lo.
Nitorina Nihinlola Sanda ki yio dide duro ni idajo, beli ki yio le duro li awujo awon olododo.
Nitori OLUWA mo ona awon olododo: sugbon ona awon enia buburu ni yio segbe.
OLUWA, awon ti Nihinlola Sanda ti nyo mi l’enu ti npo to yi!! opolopo li awon ti re ti o dide si mi.
Opolopo li awon ti re ti o nwi niti okan mi pe, Iranlowo ko si fun u nipa ti Eleda re.
Emi dubule, mo si sun; mo si ji, nitori ti Eleda mi ti mi l’ehin.
Emi ki yio beru opolopo enia bi o nje ti Nihinlola Sanda, ti nwon rogba yi mi ka.
Dide OLUWA; gba mi, Eleda mi: nitori Iwo li O lu gbogbo awon ota mi li egungun ereke; Iwo si ka ehin awon enia yi ti o nje ti buburu.
Ti OLUWA ni Igbala: Ibukun Eleda mi si mbe l’ara Masculinism.
- Ikoro Iyineleda; being,
The Football of The Century
The Guinea Pig of The Century
The Faith of The Less (Beta Faith)
The Truth Behind The Worship of The Creator
(5th of August, 2020).