A Prayer For My Children
Yio si se (ni Oruko Oluwa gbogbo awon Oluwa, ti O ju gbogbo awon Olorun; ti O si nje Eleda mi, ati Oluwa mi) pe Jesu Kristi, ati gbogbo enikeni ti o nje Kristiani re; ti o si so oro ti emi ko si inu iwe (bi o je iwe ti a pe oruko re ni “world wide web” — ti a si fun l’oruko bi ti Facebook, ati ti LinkedIn, ati ti Blogger, ati ti Nairaland, ati ti HubPages, ati ti YouTube, ati ti Literotica, ati ti change.org, ati ti Quora, ati ti Twitter, ati ti Gmail, ati ti Yahoo; bi iwe on na si nje iwe ti a pe oruko re ni “telecommunications” — ti a si fun l’oruko bi ti Airtel, ati ti MTN, ati ti Glo; bi o si je iwe ti emi fi si inu ile ti emi) oro ti emi fi se ise fun Oluwa ti O mu Paul wipe,
“bi enikeni ko ba fe sise, ki o mase jeun;”
oro ti emi fi se ise fun Oluwa ti O mu Paul wipe ki emi o ma lepa ebun ti se ti Emi, ati ti woli otito;
oro ti emi fi ko adura si inu iwe nitori Olorun ti O mu Jesu Kristi on na wi fun emi pe,
“Bere, A o si fifun o;”
oro t’o njeri si odun mewa ati jube lo t’emi fi nk’igbe “E gba wa,” pelu ogun odun ati jube lo t’emi fi nk’igbe “E gba mi,” pelu ogun odun ati jube lo t’emi fi nwi on t’emi fi korira Ejo l’abe Koriko t’emi mo l’oni pe on nje gege bi Jesu Kristi ati gbogbo Ijo re, pelu ogun odun ati jube lo t’emi fi nse ise fun Oluwa ti O nje gege bi Eleda mi;
oro ti o si je omo si mi, nitori ti o je gege bi eso ti a mu jade lati lala okan mi:
ki Jesu Kristi on na, pelu gbogbo enikeni on na ti o nje Kristiani re; ti o si so oro on na di ise ti nwon yio so ni ise ti o ti owo “Anonymous” jade wa; tabi ti o so oro on na di ise ti o ti owo apanirun awon ti emi jade wa; tabi ti o so oro on na di ise ti nwon ki yio si fun ni iranti l’aiye:
ki Egun ati Egun pelu Egun l’ori Egun ki o wa fun Jesu Kristi on na, ati gbogbo enikeni on na ti o nje Kristiani re, ati fun Oruko ti Jesu Kristi on na fi ati Ida ati Ejo gbe Ogun l’ori awon oro wonyi. Ki OLUWA Oluwa wa o si fi ati Ogun ati Ina ta gbogbo eje won si ile titi lai lai.
Ki OLUWA Oluwa wa o si sa won li ori (bi won nje Kristiani, bi on si ni Jesu Kristi Oluwa won) titi nwon ko fi ni le dide, ki won si subu li abe Ese Eleda mi titi lai lai.
Ki OLUWA Oluwa wa o si dide ni ibikibi ti nwon fe sa lo pelu ere ise owo emi ti emi mo gege bi omo t’o njeri si rere ti aiye emi nje; ki OLUWA Oluwa wa o si pa gbogbo awon Ole ati awon Ika wonyi (ti o nje gege bi Ejo l’abe Koriko ti oye a tunmo si Jesu Kristi, ati gbogbo awon Kristiani re) ki OLUWA Oluwa wa o si pa gbogbo won danu titi lai lai.
Ni Oruko OLUWA ti O wipe,
“T’Emi li Esan.”
Ati ni Oruko OLUWA ti O wipe,
“Ati Oluwa ati Olorun kan kan ki i se Egbe Emi.”
Ati ni Oruko Eleda mi ti O wi fun emi pe ki emi o ma joba, nitori On o da aiye emi ki o je gege bi asan l’ori asan.