A Prayer For My Children
Yio si se (ni Oruko Oluwa gbogbo awon Oluwa, ti O ju gbogbo awon Olorun; ti O si nje Eleda mi, ati Oluwa mi) pe gbogbo enikeni ti o ba so oro ti emi ko si inu iwe (bi o je iwe ti a pe oruko re ni “world wide web,” bi iwe on na si nje iwe ti a pe oruko re ni “telecommunications,” bi o si je iwe ti emi fi si inu ile ti emi) oro ti emi fi se ise fun Oluwa ti O mu Paul wipe,
“bi enikeni ko ba fe sise, ki o mase jeun;”
oro ti emi fi se ise fun Oluwa ti O mu Paul wipe ki emi o ma lepa ebun ti i se ti Emi, ati ti woli otito;
oro ti emi fi ko adura si inu iwe nitori Olorun ti O mu Jesu Kristi wi fun mi pe,
“Bere, A o si fifun o;”
oro t’o njeri si odun mewa ati jube lo t’emi fi nk’igbe “E gba wa,” pelu ogun odun ati jube lo t’emi fi nk’igbe “E gba mi,” pelu ogun odun ati jube lo t’emi fi nwi on t’emi fi korira Ejo l’abe Koriko t’emi mo l’oni pe on nje gege bi Jesu Kristi ati gbogbo Ijo re, pelu ogun odun ati jube lo t’emi fi nse ise fun Oluwa ti O nje gege bi Eleda mi;
oro ti o si je omo si mi, nitori ti o je gege bi eso ti a mu jade lati lala okan mi:
ki enikeni na ti o ba so oro na di ise ti nwon yio so ni ise ti o ti owo “Anonymous” jade wa; ati enikeni na ti o ba so oro na di ise ti o ti owo apanirun awon ti emi jade wa; ati enikeni na ti o ba so oro na di ise ti nwon ki yio si fun ni iranti l’aiye:
ki egun ati egun pelu egun l’ori egun ki o wa fun gbogbo awon enikeni on na titi lai lai; ki gbogbo awon enikeni on na ki o si di oku titi lai lai, ki kokoro gbogbo awon enikeni on na ki o ma ku titi lai lai; ki gbogbo awon enikeni on na si je ohun irira si gbogbo ohun mimo ati rere titi lai lai, ki gbogbo awon ohun mimo ati rere wonyi ki won si korira gbogbo awon enikeni on na titi lai lai; ki won si so gbogbo won di Eni Ihoho niwon ti o se ri, niwon ti o si se ka; nitori bi o ti po to — ki gbogbo on ti o si nje ihoho l’ana ati l’oni ati l’ola ki o si je ti gbogbo awon enikeni on na; ki won si fi ina sun gbogbo won pata pata titi gbogbo awon enikeni on na, ni ibikibi on na — l’aiye, l’Orun, l’abe ile — yio fi di oku ti o ti ku titi lai lai lati owo Iku Keji.
Gbogbo awon ti emi ti iru eni na si so di oniranu, tabi alakowe, tabi oku igbe; nwon si jade lo, nwon si wo oku gbogbo awon eni on na ti o ti sote si Oluwa ti O nje Eleda mi, nigbati nwon wipe awon sote si emi ati baba mi: nitori kokoro won ki yio ku, beni ina won ki yio si ku; nwon o si je ohun irira si gbogbo eran-ara.
Gbogbo egun wonyi yio si wa sori awon gbogbo eni wonyi, yio si lepa won, yio si ba won, titi nwon fi run; nitoriti gbogbo won fun ti emi ki i wa bikose lati jale, ati lati pa, ati lati parun.
Ni Oruko Oluwa ti O wipe emi ko gbodo pania, beni emi ko gbodo jale, beni emi ko gbodo sojukokoro si ile enikeji mi. Ati ni Oruko Oluwa ti O fun Solomon ni ogbon ati oye ti o fi wipe ole (bi o jale lati te okan re lorun, nigbati ebi npa a) yio san a pada niwon meje; gbogbo ohun ile re ni yio fi san esan. Ati ni Oruko Olorun ti O mu Jesu Kristi wi fun mi pe,
“Olorun ki yio ha si gbesan awon ayanfe Re, ti nfi osan ati oru kigbe pe E, ti O si mu suru fun won?
“Mo wi fun nyin, Yio gbesan won kankan.”
Ati ni Oruko Oluwa gbogbo awon Oluwa, ti O ju gbogbo awon Olorun; ti O si nje Eleda mi, ati Oluwa mi: ti O si wi fun mi pe,
“Nitori gege bi awon Orun titun, ati aiye titun, ti Emi O se, yio ma duro niwaju Mi, beni iru-omo re ati oruko re yio duro.”
In The Name of The LORD that saith unto me,
“For as the new Heavens and the new earth
which I will make
shall remain before Me, says The LORD;
so shall your descendants and your
name remain.
From new moon to new moon,
and from Sabbath to Sabbath,
all flesh shall come to worship before Me,
says The LORD.
“And they shall go forth and look on the dead bodies of the men that have rebelled against Me; for their worm shall not die, their fire shall not be quenched, and they shall be an abhorrence to all flesh.”